temidayoo7

Temidayo (ID Verified)

MÍMỌ̀Ọ́KỌ ÀTI MÍMỌ̀Ọ́KÀ ÈDÈ YORÙBÁ ṢÌ ṢE PÀTÀKÌ PÚPÒ LÁWÙJỌ WA

  • 90 Hours Taught
  • lekki, Lagos
  • (3)

How I can help

Yoruba Language

More than 1 year experience

MO SISE GEGE BI ATUMO ATI ONIROYIN EDE YORUBA NI ILE ISE REDIO KEREJE TOWA NINU OGBA ILE EKO TI GBOGBONISE POLI IBADAN EYI TI JE KI N TUBO DI OJAFAFA NINU OYE ATI IMO IJINLE
EDE YORUBA NITORIPE ISE TI MO N SE SOO DI ORANYAN FUN MI LATI LOYE AWON ORO NI EDE GEESI, KI NSI WA ORO TABI APOLA ORO TO SOJU ABE NI KOO LATI FI ROPO ORO EDE GEESI NAA.
BAKAN NAA LATI IBERE SAA ETO EKO MI NI EKA SOROSORO ATI IGBOHUNSAFEFE (MASS COMMUNICATION) NI MO FI KO NIPA EKO EDE YORUBA NINU OGBA ILEKO NAA. MO KO NIPA GIRAMA EDE YORUBA, LITIRESO EDEYORUBA, ASA ATI ISE EDE YORUBA ATI AMULO EDE YORUBA NINU ISE IKANSIRAENI. AWON ISORI EKO WONYI NI MO FAKOYO TI MO GBA MAAKI TO JU TI GBOGBO AKEEKO YOOKU LO.
NINU OGBA ILE IWE, MONI AWON AKEEKO TI MO MAA N KO NI EDE YORUBA TI WON SI GBA PE IRANLOWO TI MO SE FUN WON LO MU KAWON LE SASEYORI NINU IDAWON WON.

Temidayo also teaches:
English Language

Levels taught: Primary, Jss, Sss, Undergraduate and Adult

Teaching Curriculum: Nigerian

Travel Policy

Lessons hold at a neutral location

When you book lessons, they'll be delivered at your home or anywhere else you both agree - whichever works best for you.

Education History

OND in Mass Communication

The Polytechnic Ibadan

HND in Mass Communication

Adeseun Ogundoyin Polytechnic

Certificate & Awards

BEST YORUBA NEWS CASTER (TWICE) YEAR 2014 AND 2015

ASSOCIATION OF STUDENT COMMUNICATORS (ASCOM) OF THE POLYTECHNIC IBADAN

About Temidayo

Private Yoruba Language Tutor in lekki, Lagos


3 Reviews
(5.0/5.0)



Request Tutor


+234

Place a request explaining your needs and we'll connect you with Temidayo in no time.

  Identity Verified
 Discount Applies for Extra Students
Request Tutor →

Got Questions?


info@tuteria.com 080 928 78388